Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Sáàmù 144:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 144 Ìyìn ni fún Jèhófà, Àpáta mi,+Ẹni tó ń kọ́ ọwọ́ mi ní ìjàÀti ìka mi ní ogun.+
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+