-
Léfítíkù 26:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “‘Tí ẹ ò bá wá fetí sí mi lẹ́yìn èyí, ṣe ni màá fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ yín jẹ yín ní ìlọ́po méje.
-
-
Léfítíkù 26:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Lásán ni ẹ máa lo gbogbo agbára yín, torí ilẹ̀ yín kò ní mú èso rẹ̀ jáde,+ àwọn igi ilẹ̀ yín kò sì ní so èso.
-