ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 23:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Orúkọ àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú+ nìyí: Joṣebi-báṣébétì tó jẹ́ Tákímónì, olórí àwọn mẹ́ta náà.+ Ìgbà kan wà tó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ (800) ọkùnrin.

  • 1 Kíróníkà 11:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn tó jẹ́ olórí àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú nìyí, àwọn àti gbogbo Ísírẹ́lì ló tì í lẹ́yìn nínú ìjọba rẹ̀, kí wọ́n lè fi í jọba gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa Ísírẹ́lì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́