1 Kíróníkà 29:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ọba Dáfídì sọ fún gbogbo ìjọ náà pé: “Sólómọ́nì ọmọ mi, ẹni tí Ọlọ́run yàn,+ jẹ́ ọ̀dọ́, kò ní ìrírí,*+ iṣẹ́ náà sì pọ̀, torí pé kì í ṣe tẹ́ńpìlì* èèyàn, àmọ́ ti Jèhófà Ọlọ́run ni.+ Jeremáyà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ṣùgbọ́n mo sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Mi ò mọ ọ̀rọ̀ sọ,+ ọmọdé* lásán ni mí.”+
29 Ọba Dáfídì sọ fún gbogbo ìjọ náà pé: “Sólómọ́nì ọmọ mi, ẹni tí Ọlọ́run yàn,+ jẹ́ ọ̀dọ́, kò ní ìrírí,*+ iṣẹ́ náà sì pọ̀, torí pé kì í ṣe tẹ́ńpìlì* èèyàn, àmọ́ ti Jèhófà Ọlọ́run ni.+