-
1 Kíróníkà 29:23-25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Jèhófà+ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò Dáfídì bàbá rẹ̀, ó ṣàṣeyọrí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ń ṣègbọràn sí i. 24 Gbogbo àwọn ìjòyè,+ àwọn jagunjagun tó lákíkanjú+ àti gbogbo àwọn ọmọ Ọba Dáfídì+ fi ara wọn sábẹ́ Ọba Sólómọ́nì. 25 Jèhófà sọ Sólómọ́nì di ẹni ńlá tó ta yọ lójú gbogbo Ísírẹ́lì, ó sì fi iyì ọba dá a lọ́lá débi pé kò sí ọba kankan ní Ísírẹ́lì tó nírú iyì bẹ́ẹ̀ rí.+
-