Ìṣe 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí náà, wọ́n kọ́ Mósè ní gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Íjíbítì. Kódà, ó di alágbára ní ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe.+
22 Nítorí náà, wọ́n kọ́ Mósè ní gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Íjíbítì. Kódà, ó di alágbára ní ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe.+