Ẹ́kísódù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Kí o fi aṣọ ìdábùú náà kọ́ sábẹ́ àwọn ìkọ́, kí o sì gbé àpótí Ẹ̀rí náà+ wọnú ibi tí aṣọ ìdábùú náà bò. Aṣọ ìdábùú náà ni kí ẹ fi pín Ibi Mímọ́+ àti Ibi Mímọ́ Jù Lọ.+
33 Kí o fi aṣọ ìdábùú náà kọ́ sábẹ́ àwọn ìkọ́, kí o sì gbé àpótí Ẹ̀rí náà+ wọnú ibi tí aṣọ ìdábùú náà bò. Aṣọ ìdábùú náà ni kí ẹ fi pín Ibi Mímọ́+ àti Ibi Mímọ́ Jù Lọ.+