-
1 Kíróníkà 28:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Lẹ́yìn náà, Dáfídì fún Sólómọ́nì ọmọ rẹ̀ ní àwòrán ìkọ́lé+ ti ibi àbáwọlé*+ àti ti àwọn ilé rẹ̀, àwọn yàrá tí wọ́n ń kó nǹkan pa mọ́ sí, àwọn yàrá orí òrùlé, àwọn yàrá inú àti ti ilé ìbòrí ìpẹ̀tù.*+ 12 Ó fún un ní àwòrán ìkọ́lé gbogbo ohun tí a fi hàn án nípa ìmísí* nípa àwọn àgbàlá+ ilé Jèhófà, ti gbogbo àwọn yàrá ìjẹun tó yí i ká, ti àwọn ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́ àti ti àwọn ibi ìṣúra tí wọ́n ń kó àwọn ohun tí a sọ di* mímọ́+ sí;
-