1 Kíróníkà 9:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn olórí* aṣọ́bodè mẹ́rin ló wà ní ipò ẹni tó ṣeé fọkàn tán. Ọmọ Léfì ni wọ́n, àwọn ló sì ń bójú tó àwọn yàrá* àti àwọn ibi ìṣúra tó wà nínú ilé Ọlọ́run tòótọ́.+ 1 Kíróníkà 26:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní ti àwọn ọmọ Léfì, Áhíjà ló ń bójú tó àwọn ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́ àti àwọn ibi ìṣúra tí wọ́n ń kó àwọn ohun tí a sọ di* mímọ́+ sí.
26 Àwọn olórí* aṣọ́bodè mẹ́rin ló wà ní ipò ẹni tó ṣeé fọkàn tán. Ọmọ Léfì ni wọ́n, àwọn ló sì ń bójú tó àwọn yàrá* àti àwọn ibi ìṣúra tó wà nínú ilé Ọlọ́run tòótọ́.+
20 Ní ti àwọn ọmọ Léfì, Áhíjà ló ń bójú tó àwọn ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́ àti àwọn ibi ìṣúra tí wọ́n ń kó àwọn ohun tí a sọ di* mímọ́+ sí.