2 Kíróníkà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 àwọn garawa, àwọn ṣọ́bìrì, àwọn àmúga+ àti gbogbo àwọn nǹkan èlò wọn ni Hiramu-ábífì+ fi bàbà dídán ṣe fún Ọba Sólómọ́nì fún ilé Jèhófà.
16 àwọn garawa, àwọn ṣọ́bìrì, àwọn àmúga+ àti gbogbo àwọn nǹkan èlò wọn ni Hiramu-ábífì+ fi bàbà dídán ṣe fún Ọba Sólómọ́nì fún ilé Jèhófà.