ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 2:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Wò ó, mo ti rán ọkùnrin ọ̀jáfáfá oníṣẹ́ ọnà kan sí ọ, ó ní òye, Hiramu-ábì+ ni orúkọ rẹ̀, 14 ó jẹ́ ọmọ obìnrin kan tó wá látinú ẹ̀yà Dánì, àmọ́ tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ará Tírè; ó já fáfá nínú iṣẹ́ ọnà wúrà, fàdákà, bàbà, irin, òkúta, igi gẹdú, òwú aláwọ̀ pọ́pù, fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, aṣọ àtàtà àti aṣọ rírẹ̀dòdò.+ Ó lè fín oríṣiríṣi iṣẹ́ ọnà, ó sì lè ṣe iṣẹ́ ọnà èyíkéyìí tí wọ́n bá fún un.+ Ó máa ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ọ̀jáfáfá oníṣẹ́ ọnà rẹ àti àwọn ọ̀jáfáfá oníṣẹ́ ọnà olúwa mi Dáfídì bàbá rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́