1 Àwọn Ọba 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yìí, Ádóníjà+ ọmọkùnrin Hágítì ń gbé ara rẹ̀ ga, ó ń sọ pé: “Èmi ló máa di ọba!” Ó ní kí wọ́n ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún òun, ó kó àwọn agẹṣin jọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+ 1 Àwọn Ọba 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú Jóábù ọmọ Seruáyà àti àlùfáà Ábíátárì,+ wọ́n ran Ádóníjà lọ́wọ́, wọ́n sì tì í lẹ́yìn.+
5 Ní àkókò yìí, Ádóníjà+ ọmọkùnrin Hágítì ń gbé ara rẹ̀ ga, ó ń sọ pé: “Èmi ló máa di ọba!” Ó ní kí wọ́n ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún òun, ó kó àwọn agẹṣin jọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+
7 Ó lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú Jóábù ọmọ Seruáyà àti àlùfáà Ábíátárì,+ wọ́n ran Ádóníjà lọ́wọ́, wọ́n sì tì í lẹ́yìn.+