1 Àwọn Ọba 7:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó fi bàbà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹrù*+ mẹ́wàá. Gígùn kẹ̀kẹ́ ẹrù kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta.
27 Ó fi bàbà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹrù*+ mẹ́wàá. Gígùn kẹ̀kẹ́ ẹrù kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta.