-
2 Àwọn Ọba 25:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ní ti àwọn òpó méjèèjì àti Òkun pẹ̀lú àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù tí Sólómọ́nì ṣe fún ilé Jèhófà, bàbà tó wà lára gbogbo àwọn nǹkan èlò yìí kọjá wíwọ̀n.+
-