1 Àwọn Ọba 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó mọ òpó bàbà méjì;+ gíga òpó kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjìdínlógún (18), okùn ìwọ̀n ìgbọ̀nwọ́ méjìlá (12) lè yí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn òpó náà ká.*+ 1 Àwọn Ọba 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ṣe àwọn òpó ibi àbáwọlé* tẹ́ńpìlì.*+ Ó ṣe òpó apá ọ̀tún,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jákínì,* lẹ́yìn náà, ó ṣe òpó apá òsì,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bóásì.*+
15 Ó mọ òpó bàbà méjì;+ gíga òpó kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjìdínlógún (18), okùn ìwọ̀n ìgbọ̀nwọ́ méjìlá (12) lè yí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn òpó náà ká.*+
21 Ó ṣe àwọn òpó ibi àbáwọlé* tẹ́ńpìlì.*+ Ó ṣe òpó apá ọ̀tún,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jákínì,* lẹ́yìn náà, ó ṣe òpó apá òsì,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bóásì.*+