Sáàmù 148:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+ Jeremáyà 23:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Ṣé ibì kan wà téèyàn lè sá pa mọ́ sí tí mi ò ní lè rí i?”+ ni Jèhófà wí. “Ǹjẹ́ ohunkóhun wà láyé tàbí lọ́run tí ojú mi ò tó?”+ ni Jèhófà wí.
13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+
24 “Ṣé ibì kan wà téèyàn lè sá pa mọ́ sí tí mi ò ní lè rí i?”+ ni Jèhófà wí. “Ǹjẹ́ ohunkóhun wà láyé tàbí lọ́run tí ojú mi ò tó?”+ ni Jèhófà wí.