Sáàmù 139:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ibo ni mo lè sá sí tí màá fi bọ́ lọ́wọ́ ẹ̀mí rẹ,Ibo ni mo sì lè sá lọ kí ojú rẹ má bàa tó mi?+