1 Àwọn Ọba 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (3,300) ìjòyè+ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ àbójútó láti máa darí àwọn òṣìṣẹ́. 2 Kíróníkà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí náà, ó yan ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) lára wọn láti ṣe lébìrà* àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin (80,000) láti máa gé òkúta+ ní àwọn òkè àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (3,600) láti ṣe alábòójútó tí á máa kó àwọn èèyàn ṣiṣẹ́.+
16 àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (3,300) ìjòyè+ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ àbójútó láti máa darí àwọn òṣìṣẹ́.
18 Nítorí náà, ó yan ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) lára wọn láti ṣe lébìrà* àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin (80,000) láti máa gé òkúta+ ní àwọn òkè àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (3,600) láti ṣe alábòójútó tí á máa kó àwọn èèyàn ṣiṣẹ́.+