1 Àwọn Ọba 9:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Hírámù kó ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun+ rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn òṣìṣẹ́ ọkọ̀ òkun tó mọṣẹ́, láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì. 28 Wọ́n lọ sí Ófírì,+ wọ́n sì kó ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ogún (420) tálẹ́ńtì wúrà láti ibẹ̀ wá fún Ọba Sólómọ́nì. Sáàmù 45:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọba wà lára àwọn obìnrin ọlọ́lá rẹ. Ayaba* dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ, a fi wúrà Ófírì+ ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́.
27 Hírámù kó ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun+ rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn òṣìṣẹ́ ọkọ̀ òkun tó mọṣẹ́, láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì. 28 Wọ́n lọ sí Ófírì,+ wọ́n sì kó ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ogún (420) tálẹ́ńtì wúrà láti ibẹ̀ wá fún Ọba Sólómọ́nì.
9 Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọba wà lára àwọn obìnrin ọlọ́lá rẹ. Ayaba* dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ, a fi wúrà Ófírì+ ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́.