Léfítíkù 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà. Ìṣe 7:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Àmọ́ àgọ́ Mólókù+ àti ìràwọ̀ ọlọ́run Réfánì tí ẹ̀ ń gbé ga ni, àwọn ère tí ẹ ṣe láti máa jọ́sìn wọn. Nítorí náà, màá lé yín dà nù kọjá Bábílónì.’+
21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà.
43 Àmọ́ àgọ́ Mólókù+ àti ìràwọ̀ ọlọ́run Réfánì tí ẹ̀ ń gbé ga ni, àwọn ère tí ẹ ṣe láti máa jọ́sìn wọn. Nítorí náà, màá lé yín dà nù kọjá Bábílónì.’+