-
Àwọn Onídàájọ́ 8:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Gídíónì ọmọ Jóáṣì wá gba ọ̀nà tó lọ sí Hérésì pa dà láti ojú ogun.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó wó ilé gogoro Pénúélì,+ ó sì pa àwọn ọkùnrin ìlú náà.
-