Émọ́sì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣùgbọ́n ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì mọ́,+ nítorí pé ibùjọsìn ọba ni,+ ilé ìjọba sì ni.”