Émọ́sì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 ‘Àmọ́, ẹ̀ ń fún Násírì ní wáìnì mu,+Ẹ sì ń pàṣẹ fún àwọn wòlíì pé: “Ẹ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀.”+