1 Àwọn Ọba 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+ 2 Kíróníkà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kò pẹ́ lẹ́yìn tí ìjọba Rèhóbóámù fìdí múlẹ̀,+ tí ó sì di alágbára, ó pa Òfin Jèhófà tì,+ òun àti gbogbo Ísírẹ́lì.
7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+
12 Kò pẹ́ lẹ́yìn tí ìjọba Rèhóbóámù fìdí múlẹ̀,+ tí ó sì di alágbára, ó pa Òfin Jèhófà tì,+ òun àti gbogbo Ísírẹ́lì.