Jóṣúà 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìgbà yẹn ni Jóṣúà búra* pé: “Níwájú Jèhófà, ègún ni fún ẹni tó bá gbìyànjú láti tún ìlú Jẹ́ríkò yìí kọ́. Tó bá fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀, ẹ̀mí àkọ́bí rẹ̀ ló máa fi dí i, tó bá sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró, ẹ̀mí àbíkẹ́yìn rẹ̀ ló máa fi dí i.”+
26 Ìgbà yẹn ni Jóṣúà búra* pé: “Níwájú Jèhófà, ègún ni fún ẹni tó bá gbìyànjú láti tún ìlú Jẹ́ríkò yìí kọ́. Tó bá fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀, ẹ̀mí àkọ́bí rẹ̀ ló máa fi dí i, tó bá sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró, ẹ̀mí àbíkẹ́yìn rẹ̀ ló máa fi dí i.”+