-
Nọ́ńbà 11:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Tó bá jẹ́ ohun tí o fẹ́ ṣe fún mi nìyí, jọ̀ọ́ kúkú pa mí báyìí.+ Tí mo bá rí ojúure rẹ, má ṣe jẹ́ kí ojú mi tún rí ibi mọ́.”
-
-
Jóòbù 3:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Kí ló dé tí wọ́n ń retí ikú, àmọ́ tí kò dé?+
Wọ́n ń wá a ju bí wọ́n ṣe ń wá ìṣúra tó fara pa mọ́ sínú ilẹ̀,
-