Ẹ́kísódù 22:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “O ò gbọ́dọ̀ sọ̀rọ̀ òdì sí* Ọlọ́run+ tàbí kí o sọ̀rọ̀ òdì sí ìjòyè* nínú àwọn èèyàn rẹ.+