ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 22:37, 38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Bí ọba ṣe kú nìyẹn, wọ́n gbé e wá sí Samáríà, wọ́n sì sin ín sí Samáríà. 38 Nígbà tí wọ́n fọ kẹ̀kẹ́ ogun náà létí adágún odò tó wà ní Samáríà, àwọn ajá lá ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, àwọn aṣẹ́wó sì wẹ̀ níbẹ̀,* gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ.+

  • 2 Àwọn Ọba 9:25, 26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Jéhù wá sọ fún Bídíkárì tó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ lójú ogun pé: “Gbé e, kí o sì jù ú sínú ilẹ̀ Nábótì ará Jésírẹ́lì.+ Rántí pé èmi pẹ̀lú rẹ jọ ń gun ẹṣin* tẹ̀ lé Áhábù bàbá rẹ̀ nígbà tí Jèhófà fúnra rẹ̀ kéde ìdájọ́ lé e lórí pé:+ 26 ‘“Bí mo ṣe rí ẹ̀jẹ̀ Nábótì+ àti ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọ rẹ̀ lánàá,” ni Jèhófà wí, “màá san án pa dà+ fún ọ ní ilẹ̀ yìí kan náà,” ni Jèhófà wí.’ Torí náà, gbé e, kí o sì jù ú sórí ilẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́