1 Àwọn Ọba 21:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Ṣé o rí bí Áhábù ṣe rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí mi?+ Torí pé ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ níwájú mi, mi ò ní mú àjálù náà wá nígbà ayé rẹ̀. Ìgbà ayé ọmọ rẹ̀ ni màá mú àjálù náà wá sórí ilé rẹ̀.”+
29 “Ṣé o rí bí Áhábù ṣe rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí mi?+ Torí pé ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ níwájú mi, mi ò ní mú àjálù náà wá nígbà ayé rẹ̀. Ìgbà ayé ọmọ rẹ̀ ni màá mú àjálù náà wá sórí ilé rẹ̀.”+