20 “‘Síbẹ̀, àwọn ohun kan wà tí mo rí tí ò ń ṣe tí kò dáa, o fàyè gba Jésíbẹ́lì+ obìnrin yẹn, ẹni tó pe ara rẹ̀ ní wòlíì obìnrin, tó ń kọ́ àwọn ẹrú mi, tó sì ń ṣì wọ́n lọ́nà kí wọ́n lè ṣe ìṣekúṣe,+ kí wọ́n sì jẹ àwọn nǹkan tí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà.