6 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sin àwọn Báálì,+ àwọn ère Áṣítórétì, àwọn ọlọ́run Árámù, àwọn ọlọ́run Sídónì, àwọn ọlọ́run Móábù,+ àwọn ọlọ́run àwọn ọmọ Ámónì+ àti àwọn ọlọ́run àwọn Filísínì.+ Wọ́n fi Jèhófà sílẹ̀, wọn ò sì sìn ín.