1 Àwọn Ọba 14:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà yóò kọ lu Ísírẹ́lì, á sì dà bí esùsú* tó ń mì lòólòó lójú omi, yóò fa Ísírẹ́lì tu kúrò lórí ilẹ̀ dáradára yìí tó fún àwọn baba ńlá wọn,+ yóò sì tú wọn ká kọjá Odò,*+ nítorí wọ́n ṣe àwọn òpó òrìṣà,*+ tí wọ́n sì ń mú Jèhófà bínú. 1 Àwọn Ọba 16:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Áhábù tún ṣe òpó òrìṣà.*+ Áhábù sì ṣe ohun tó bí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì nínú ju gbogbo àwọn ọba Ísírẹ́lì tó jẹ ṣáájú rẹ̀ lọ.
15 Jèhófà yóò kọ lu Ísírẹ́lì, á sì dà bí esùsú* tó ń mì lòólòó lójú omi, yóò fa Ísírẹ́lì tu kúrò lórí ilẹ̀ dáradára yìí tó fún àwọn baba ńlá wọn,+ yóò sì tú wọn ká kọjá Odò,*+ nítorí wọ́n ṣe àwọn òpó òrìṣà,*+ tí wọ́n sì ń mú Jèhófà bínú.
33 Áhábù tún ṣe òpó òrìṣà.*+ Áhábù sì ṣe ohun tó bí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì nínú ju gbogbo àwọn ọba Ísírẹ́lì tó jẹ ṣáájú rẹ̀ lọ.