-
1 Àwọn Ọba 15:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Níkẹyìn, Ásà sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú wọn ní Ìlú Dáfídì baba ńlá rẹ̀; Jèhóṣáfátì+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
-