2 Sámúẹ́lì 17:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ábúsálómù fi Ámásà+ sí ipò Jóábù+ láti máa darí àwọn ọmọ ogun; Ámásà jẹ́ ọmọ ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ítírà, ọmọ Ísírẹ́lì ni Ítírà, òun ló ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú Ábígẹ́lì+ ọmọ Náháṣì, arábìnrin Seruáyà, ìyá Jóábù.
25 Ábúsálómù fi Ámásà+ sí ipò Jóábù+ láti máa darí àwọn ọmọ ogun; Ámásà jẹ́ ọmọ ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ítírà, ọmọ Ísírẹ́lì ni Ítírà, òun ló ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú Ábígẹ́lì+ ọmọ Náháṣì, arábìnrin Seruáyà, ìyá Jóábù.