Hébérù 11:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Àwọn obìnrin rí àwọn òkú wọn gbà nípa àjíǹde,+ àmọ́ wọ́n dá àwọn ọkùnrin míì lóró torí pé wọn ò gbà kí wọ́n tú àwọn sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà, kí ọwọ́ wọn lè tẹ àjíǹde tó dáa jù.
35 Àwọn obìnrin rí àwọn òkú wọn gbà nípa àjíǹde,+ àmọ́ wọ́n dá àwọn ọkùnrin míì lóró torí pé wọn ò gbà kí wọ́n tú àwọn sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà, kí ọwọ́ wọn lè tẹ àjíǹde tó dáa jù.