ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 17:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Obìnrin náà wá sọ fún Èlíjà pé: “Mo ti wá mọ̀ báyìí pé èèyàn Ọlọ́run+ ni ọ́ lóòótọ́ àti pé ọ̀rọ̀ Jèhófà tó wà lẹ́nu rẹ jẹ́ òótọ́.”

  • 1 Àwọn Ọba 19:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Kí o fòróró yan Jéhù+ ọmọ ọmọ Nímúṣì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì, kí o sì yan Èlíṣà* ọmọ Ṣáfátì láti Ebẹli-méhólà ṣe wòlíì ní ipò rẹ.+

  • 2 Àwọn Ọba 3:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ni Jèhóṣáfátì bá sọ pé: “Ṣé kò sí wòlíì Jèhófà níbí tó lè bá wa wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà ni?”+ Torí náà, ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ ọba Ísírẹ́lì dáhùn pé: “Èlíṣà+ ọmọ Ṣáfátì, ẹni tó máa ń bu omi sí ọwọ́ Èlíjà*+ wà níbí.” 12 Lẹ́yìn náà, Jèhóṣáfátì sọ pé: “Ọ̀rọ̀ Jèhófà wà lẹ́nu rẹ̀.” Torí náà, ọba Ísírẹ́lì àti Jèhóṣáfátì àti ọba Édómù lọ bá a.

  • 2 Àwọn Ọba 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà náà, ọba ń bá Géhásì ìránṣẹ́ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, ó ní: “Jọ̀wọ́, ròyìn fún mi nípa gbogbo ohun ńlá tí Èlíṣà ti ṣe.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́