Lúùkù 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bákan náà, ọ̀pọ̀ adẹ́tẹ̀ ló wà ní Ísírẹ́lì nígbà ayé wòlíì Èlíṣà; síbẹ̀ a ò wẹ ìkankan nínú wọn mọ́,* àfi Náámánì ará Síríà.”+ Lúùkù 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fọwọ́ kàn án, ó ní: “Mo fẹ́ bẹ́ẹ̀! Kí o mọ́.” Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ẹ̀tẹ̀ náà pòórá lára rẹ̀.+
27 Bákan náà, ọ̀pọ̀ adẹ́tẹ̀ ló wà ní Ísírẹ́lì nígbà ayé wòlíì Èlíṣà; síbẹ̀ a ò wẹ ìkankan nínú wọn mọ́,* àfi Náámánì ará Síríà.”+
13 Torí náà, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fọwọ́ kàn án, ó ní: “Mo fẹ́ bẹ́ẹ̀! Kí o mọ́.” Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ẹ̀tẹ̀ náà pòórá lára rẹ̀.+