2 Àwọn Ọba 8:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ lọ́jọ́ kejì, Hásáẹ́lì mú aṣọ tí wọ́n ń dà bo ibùsùn, ó tẹ̀ ẹ́ bọ omi, ó sì fi bo ojú olúwa rẹ̀ mọ́lẹ̀* títí ó fi kú.+ Hásáẹ́lì sì di ọba ní ipò rẹ̀.+
15 Àmọ́ lọ́jọ́ kejì, Hásáẹ́lì mú aṣọ tí wọ́n ń dà bo ibùsùn, ó tẹ̀ ẹ́ bọ omi, ó sì fi bo ojú olúwa rẹ̀ mọ́lẹ̀* títí ó fi kú.+ Hásáẹ́lì sì di ọba ní ipò rẹ̀.+