ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 16:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní ọdún kẹrìndínlọ́gbọ̀n Ásà ọba Júdà, Élà ọmọ Bááṣà di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Tírísà, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso.

  • 1 Àwọn Ọba 16:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Símírì wọlé, ó ṣá a balẹ̀,+ ó sì pa á ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n Ásà ọba Júdà, ó sì jọba ní ipò rẹ̀.

  • 2 Àwọn Ọba 11:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nígbà tí Ataláyà,+ ìyá Ahasáyà rí i pé ọmọ òun ti kú,+ ó dìde, ó sì pa gbogbo ìdílé ọba* run.+

  • 2 Àwọn Ọba 15:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní ọdún kejìdínlógójì Asaráyà+ ọba Júdà, Sekaráyà+ ọmọ Jèróbóámù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ó sì fi oṣù mẹ́fà ṣàkóso.

  • 2 Àwọn Ọba 15:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìgbà náà ni Ṣálúmù ọmọ Jábéṣì dìtẹ̀ mọ́ ọn, ó sì pa á+ ní Íbíléámù.+ Lẹ́yìn tó pa á, ó jọba ní ipò rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́