1 Àwọn Ọba 16:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà tí ó jọba, gbàrà tí ó gorí ìtẹ́, ó pa gbogbo ará ilé Bááṣà. Kò fi ọkùnrin* kankan sílẹ̀, ì báà jẹ́ ìbátan* rẹ̀ tàbí ọ̀rẹ́ rẹ̀. 12 Bí Símírì ṣe pa gbogbo ilé Bááṣà rẹ́ nìyẹn, bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu wòlíì Jéhù kéde sórí Bááṣà.+
11 Nígbà tí ó jọba, gbàrà tí ó gorí ìtẹ́, ó pa gbogbo ará ilé Bááṣà. Kò fi ọkùnrin* kankan sílẹ̀, ì báà jẹ́ ìbátan* rẹ̀ tàbí ọ̀rẹ́ rẹ̀. 12 Bí Símírì ṣe pa gbogbo ilé Bááṣà rẹ́ nìyẹn, bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu wòlíì Jéhù kéde sórí Bááṣà.+