-
1 Àwọn Ọba 16:1-3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Jèhófà gbẹnu Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ kéde ìdájọ́ sórí Bááṣà pé: 2 “Mo gbé ọ dìde láti inú iyẹ̀pẹ̀, mo sì sọ ọ́ di aṣáájú lórí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì,+ ṣùgbọ́n ò ń rìn ní ọ̀nà Jèróbóámù, o sì mú kí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì ṣẹ̀, tí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá+ sì mú mi bínú. 3 Torí náà, màá gbá Bááṣà àti ilé rẹ̀ dà nù bí ẹni gbálẹ̀, màá sì ṣe ilé rẹ̀ bí ilé Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì.
-