2 Àwọn Ọba 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Gbogbo ilé Áhábù ló máa ṣègbé; màá sì pa gbogbo ọkùnrin* ilé Áhábù run, títí kan àwọn aláìní àti àwọn aláìníláárí ní Ísírẹ́lì.+ 2 Kíróníkà 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run fa ìṣubú Ahasáyà bó ṣe wá sọ́dọ̀ Jèhórámù; nígbà tó dé, ó tẹ̀ lé Jèhórámù lọ sọ́dọ̀ Jéhù+ ọmọ ọmọ* Nímúṣì, ẹni tí Jèhófà ti fòróró yàn láti pa ilé Áhábù run.*+
8 Gbogbo ilé Áhábù ló máa ṣègbé; màá sì pa gbogbo ọkùnrin* ilé Áhábù run, títí kan àwọn aláìní àti àwọn aláìníláárí ní Ísírẹ́lì.+
7 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run fa ìṣubú Ahasáyà bó ṣe wá sọ́dọ̀ Jèhórámù; nígbà tó dé, ó tẹ̀ lé Jèhórámù lọ sọ́dọ̀ Jéhù+ ọmọ ọmọ* Nímúṣì, ẹni tí Jèhófà ti fòróró yàn láti pa ilé Áhábù run.*+