2 Àwọn Ọba 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní ọdún keje Jéhù,+ Jèhóáṣì+ di ọba, ó sì fi ogójì (40) ọdún ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sibáyà láti Bíá-ṣébà.+
12 Ní ọdún keje Jéhù,+ Jèhóáṣì+ di ọba, ó sì fi ogójì (40) ọdún ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sibáyà láti Bíá-ṣébà.+