-
2 Àwọn Ọba 14:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ní ọdún kejì Jèhóáṣì+ ọmọ Jèhóáhásì ọba Ísírẹ́lì, Amasááyà ọmọ Jèhóáṣì ọba Júdà di ọba.
-
-
2 Àwọn Ọba 14:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà tí ìjọba rẹ̀ ti fìdí múlẹ̀ dáadáa, ó pa àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n pa bàbá rẹ̀ ọba.+
-