-
2 Kíróníkà 24:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Nígbà tí wọ́n kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ (nítorí wọ́n fi í sílẹ̀ pẹ̀lú ọgbẹ́ yán-na-yàn-na* lára), àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ dìtẹ̀ mọ́ ọn nítorí ó ti ta ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọ* àlùfáà Jèhóádà+ sílẹ̀. Wọ́n pa á lórí ibùsùn rẹ̀.+ Bó ṣe kú nìyẹn, wọ́n sì sin ín sí Ìlú Dáfídì,+ àmọ́ wọn ò sin ín sí ibi tí wọ́n ń sin àwọn ọba sí.+
-