2 Àwọn Ọba 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà náà, Amasááyà rán àwọn òjíṣẹ́ sí Jèhóáṣì ọmọ Jèhóáhásì ọmọ Jéhù ọba Ísírẹ́lì pé: “Wá, jẹ́ ká dojú ìjà kọ ara wa.”*+ 2 Àwọn Ọba 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì mú Amasááyà ọba Júdà, ọmọ Jèhóáṣì ọmọ Ahasáyà, ní Bẹti-ṣémẹ́ṣì. Lẹ́yìn náà, wọ́n wá sí Jerúsálẹ́mù, ó sì ṣe àlàfo sára ògiri Jerúsálẹ́mù láti Ẹnubodè Éfúrémù+ títí dé Ẹnubodè Igun,+ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ìgbọ̀nwọ́.*
8 Nígbà náà, Amasááyà rán àwọn òjíṣẹ́ sí Jèhóáṣì ọmọ Jèhóáhásì ọmọ Jéhù ọba Ísírẹ́lì pé: “Wá, jẹ́ ká dojú ìjà kọ ara wa.”*+
13 Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì mú Amasááyà ọba Júdà, ọmọ Jèhóáṣì ọmọ Ahasáyà, ní Bẹti-ṣémẹ́ṣì. Lẹ́yìn náà, wọ́n wá sí Jerúsálẹ́mù, ó sì ṣe àlàfo sára ògiri Jerúsálẹ́mù láti Ẹnubodè Éfúrémù+ títí dé Ẹnubodè Igun,+ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ìgbọ̀nwọ́.*