2 Àwọn Ọba 15:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n Jèróbóámù* ọba Ísírẹ́lì, Asaráyà*+ ọmọ Amasááyà+ ọba Júdà di ọba.+ 2 Ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ni nígbà tó jọba, ọdún méjìléláàádọ́ta (52) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jekoláyà tó wá láti Jerúsálẹ́mù.
15 Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n Jèróbóámù* ọba Ísírẹ́lì, Asaráyà*+ ọmọ Amasááyà+ ọba Júdà di ọba.+ 2 Ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ni nígbà tó jọba, ọdún méjìléláàádọ́ta (52) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jekoláyà tó wá láti Jerúsálẹ́mù.