Ẹ́kísódù 34:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣùgbọ́n kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ sì fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú, kí ẹ sì wó àwọn òpó òrìṣà* wọn lulẹ̀.+ Diutarónómì 16:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “O ò gbọ́dọ̀ gbin igi èyíkéyìí láti fi ṣe òpó òrìṣà*+ sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí o ṣe fún ara rẹ. 22 “O ò sì gbọ́dọ̀ ṣe ọwọ̀n òrìṣà fún ara rẹ,+ torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ kórìíra rẹ̀.
13 Ṣùgbọ́n kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ sì fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú, kí ẹ sì wó àwọn òpó òrìṣà* wọn lulẹ̀.+
21 “O ò gbọ́dọ̀ gbin igi èyíkéyìí láti fi ṣe òpó òrìṣà*+ sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí o ṣe fún ara rẹ. 22 “O ò sì gbọ́dọ̀ ṣe ọwọ̀n òrìṣà fún ara rẹ,+ torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ kórìíra rẹ̀.