-
1 Àwọn Ọba 12:31, 32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ó kọ́ àwọn ilé ìjọsìn sórí àwọn ibi gíga, ó sì yan àwọn àlùfáà látinú gbogbo àwọn èèyàn náà, àwọn tí kì í ṣe ọmọ Léfì.+ 32 Jèróbóámù tún dá àjọyọ̀ kan sílẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù náà, bí àjọyọ̀ tó wà ní Júdà.+ Ó rú ẹbọ sí àwọn ère ọmọ màlúù tó ṣe sórí àwọn pẹpẹ tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì yan àwọn àlùfáà ní Bẹ́tẹ́lì fún àwọn ibi gíga tó ṣe.
-