-
Diutarónómì 20:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kó sọ fún wọn pé, ‘Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn ọ̀tá yín lẹ fẹ́ lọ bá jagun. Ẹ má ṣojo. Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà, ẹ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá yín nítorí wọn,
-
-
Àìsáyà 51:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ẹ má bẹ̀rù bí àwọn ẹni kíkú ṣe ń pẹ̀gàn yín,
Ẹ má sì jẹ́ kí èébú wọn kó jìnnìjìnnì bá yín.
-